King Sam Miracle – Ebo Oso





King Sam Miracle, a gifted singer, has just released a new song for his admirers throughout the world titled “Ebo Oso” as a way to close out the year.

He made an attempt to harmonise the new song’s appealing beat with the thoughtfully crafted words he wrote.



This new song from King Sam Miracle is his way of saying “thank you” for all of the love and support his listeners have given him over the years, and it’s guaranteed to be a hit.

Take in the new tune with the help of the song’s lyrics as you read along. Give to your pals if you care about them








Ebo Oso Lyrics by King Sam Miracle | Official Lyrics

Strings intro Omo iya o’ni dodo, Omo iya o’ni kuli, Omo iya o’ni dodo, Omo iya o’ni kuli


Percussion: ?BO OSO, ?BO AJ?, ?BO OSO SE IRU ?BO AJ? SE IRU, ?BO ALA ROKA ROKA KO SE IRU.

Lead / Chrous: ?BO OSO SE IRU, ?BO AJ? SE IRU x2

Lead: ?BO ALAROKA YEN NKO ooo?
Chorus: KO’SE RU x2 Ko’se (RU x6)
Lead: Oh Yes
Chorus: OLORUN LO LE SEGUN OTA GBOGBO x2.

Strings Feels ?

SEGUN FUN MI, BABA SEGUN FUN MI x2
IWO NI OLUWA IWO NI OLUWA BABA SEGUN FUN MI.

Lead: GBEJA MI JA O
Chorus: GBEJA MI JA O BABA GBEJA MI JA O

Lead: L?NU IS? MI
Chorus: GBEJA MI JA O BABA GBEJA MI JA O,
Lead: Ni ILE IWE MI
Chrous: IWO NI OLWA, IWO NI OLUWA BABA GBEJA MI

Strings same Intro

Solo: OMO IYA: Tio BA PE YIN PAPO PE KE WA RO JO,
PE KI LO SE FUN GAN, TO FI RO OJO R? KI RI O.

O’LE MA NI SOJU WA NA SE BI O,
KA’BI KO NI OWO WA LO DAGBA SI O.


OWA DAGBA TAN O’SE LAULAU KIRI,
O DAGBA TAN O’SE BI OLOLA AYE O

OMO IYA ILARA NA PE YI O,
SENI KOYA FI ?JO WON SUN OLORUN OBA.
AFI KOYA FA WON LE OLORUN LOWO
Tori OLORUN LO LE SEGUN OTA GBOGBO.
Ani OLORUN LO LE SEGUN OTA GBOGBO

NI MO SE NI, EBO OSO SE IRU.
?BO AJE SE IRU. X2
?BO AWON ALAROKA YEN NKO ooo?
Chorus: KO’SE RU x2 Ko’se (RU x6)

Chorus: OLORUN LO LE SEGUN OTA GBOGBO x2.

Strings feels

SEGUN FUN MI, BABA SEGUN FUN MI x2
IWO NI OLUWA IWO NI OLUWA BABA SEGUN FUN MI.

Lead: GBEJA MI JA O
Chorus: GBEJA MI JA O BABA GBEJA MI JA O

Lead: L?NU IS? MI
Chorus: GBEJA MI JA O BABA GBEJA MI JA O,
Lead: Ni ILE IWE MI
Chrous: IWO NI OLWA, IWO NI OLUWA BABA GBEJA MI.

Lead: GBOGBO OTA TOHUN PE ORI MI N’IBI
Percussion Intro: YAGO FUN JINA SI ALAROKA.
EYI TI NBA NI J?, TI NBA NI MUN TI NSORO ?NI L? YI YI YI POROGODO. Ti soro ?ni l? yi yi yi Porogodo.

Lead: GBOGBO OTA TOHUN PE ORI MI N’IBI

Percussion: Yago fun jina si alaroka, eyin ti ba ni j?, ti ba’ni mun ti soro ?ni l?yi, yi yi yi Porogodo

GBOGBO OTA TOHUN PE ORI MI N’IBI.
GBOGBO OTA TOHUN TO ROJO MI N’IBI
N’OJU EMI MI E O PO OKUN SO
Chorus: GBOGBO OTA TOHUN PE ORI MI N’IBI
GBOGBO OTA TOHUN TO ROJO MI N’IBI
N’OJU EMI MI E O PO OKUN SO

Solo: AWON A’JE OMO J?HUN MAMA JE OMO O YO.
AWON A’JE OMO SHI’S? MA JE OMO O JERE.
AWON ENI IBI TI WON FE KA RI OGO WA LO oo.


GBOGBO OTA TOHUN PE ORI MI N’IBI
GBOGBO OTA TOHUN TO ROJO MI N’IBI
N’OJU EMI MI E MA PO OKUN SO
Chorus: GBOGBO OTA TOHUN PE ORI MI N’IBI
GBOGBO OTA TOHUN TO ROJO MI N’IBI
N’OJU EMI MI E O PO OKUN SO

Lead: Alright!! ALAROKA LEAVE ME ALONE
Chorus: MO BEBE O, TIO BA DEYI LEYI MI O, O MA TE.
Lead: KENI MAMA NI, LEAVE ME ALONE
Chorus: MO BEBE O, TIO BA DEYI LEYI MI O, O MA TE.
Lead: AFI OJU FENI MA FI OKAN FENI
Chorus: MO BEBE O, TIO BA DEYI LEYI MI O, O MA TE.

Lead: OROGUN OWO LEAVE ME ALONE!
Chorus: MO BEBE O, TIO BA DEYI LEYI MI O, O MA TEE

Post a Comment

0 Comments