[Lyrics] C Black ft. Naira Marley – Ogologo Lyrics
Lyrics
Marley naira
Pounds oun segbe dollar
Won kin no bredi no dey dull am
O wun emi na kin lo j’amala pekam
Ogologo
Ogo to le kongo
Ogologo
Ogo to le kongo
Ologo rainbow
Osha propro
Ogologo lyrical mafia emi ogbologbo
Ogologo
Mo n korin mo tun mo ijo jo
Ogologo
Mo mowo mo tun mo oju obo
Ogologo
Mo mo iwe mo tun mo Igbo we
Ogologo
Ori olori lo nlo eran Iya oshogbo
Lagbara fu ro ké lo gbé agbara le
Agbo zanku la wa ké lo bo agbara le
Iphone x mas e ma lo jé oja bo le
Awon Omo wase?
Eleha to si sardine àwo ri àwo
O fẹ wá mí wálé kò wá bà mí là gbó
Je ka rí ra Later àbí ká pàdé lá gbó
Àwa má rí má kò ẹyin ká rí ká sho
Never broke again àwọn ìjọba ceecee
Chevrolet camaro ya tó infinity
Ara utility mi ò ní gungirity
Má tá fele fele Come My vicinity
Garri ó need ìpolówó
Àti mo pé ẹni Mission
Ọlopa mú ẹ ó ní kó má gbé e gba títí
Ọmọ àṣẹ kò sá tí de Station
Ogologo
Ogo to le kongo
Ogologo
Ogo to le kongo
Ologo rainbow
Osha propro (Osha pra pra)
Ogologo
Lyrical mafia ẹ mi ogbologbo
Ogologo
Mo n korin mo tun mo ijo jo
Ogologo
Mo mowo mo tun mo oju obo
Ogologo
Mo mo we mo tun mo Igbo wé
Ogologo
Ori olori lo nlo eran Iya oshogbo
Osha lè fo fún adìẹ
Osha lè do mummy ẹ
Olosho tún lè sha Daddy ẹ
Bí Zlatan Sọ lè gbé body ẹ
A Sha lè fò fún adìẹ
Osha lè do mummy ẹ
Olosho tún lè sha Daddy ẹ o
Bí Zlatan sọ lè gbé body ẹ
Ìtumò ìtumò yẹ ìtumò ye
Abu Abel ó bá má?
Alaye ṣe bí o kàwé sebi ó Mọ wé
Ó tún wá rí ìṣe láyé
Sọ rí pé oje lọ láyé
Lọ ra lappy kò wá hacker sì Malay
Arin giniginini arin gini
Arin ginini wó ọjà
Ilé mọ wo di ilé owó
Ọna mó gbá ọ’nà mọ gbá di ọ’nà ola
Àpótí mó fi joko àpótí ajé
Ìyẹn di àpótí alaje
Òkè àgbà ní mo gùn
òkè àgbà òkè àgbà ní mó gùn
Cblack
Marlians (Mafians)
Ogologo
Ogo to le kongo
Ogologo
Ogo to le kongo
Ologo rainbow
Osha prapra
Share [Lyrics] C Black ft. Naira Marley – Ogologo Lyrics with others on social media;
0 Comments